0^MatiuÀkọsílẹ̀ ìwé ìran Jesu KristiÌtàn ibí Jesu KristiÌbẹ̀wò àwọn amòyeA gbé Jesu sálọ sì EjibitiÌpadà sí NasaretiJohanu onítẹ̀bọmi tún ọnà náà ṣeÌtẹ̀bọmi JesuÌdánwò JesuJesu bẹ̀rẹ̀ sí wàásùPípe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn àkọ́kọ́Jesu ṣe ìwòsànÌwàásù orí òkèIyọ̀ àti ìmọ́lẹ̀Ìmúṣẹ òfinÌpànìyànPanṣágàÌkọ̀sílẹ̀ÌbúraOjú fún ojúFẹ́ràn ọ̀tá rẹÌtọrẹ àánúÀdúràÀwẹ̀Títo ìṣúra jọ sí Ọ̀runẸ má ṣe àníyànṢíṣe ìdájọ́ ẹnìkejìBéèrè, kànkùn, wá kiriỌ̀nà tóóró àti ọnà gbòòròIgi àti èso rẹ̀Ọlọ́gbọ́n àti òmùgọ̀ ọ̀mọ̀léỌkùnrin adẹ́tẹ̀Ìgbàgbọ́ balógun ọ̀rúnJesu wo ọ̀pọ̀ aláìsàn sànOhun tí o gbà láti tẹ̀lé JesuJesu dá ìjì líle dúróÌwòsàn ọkùnrin ẹlẹ́mìí èṣù méjìJesu mú arọ láradáÌpè MatiuÌbéèrè nípa àwẹ̀ lọ́wọ́ JesuỌmọbìnrin tó kú àti obìnrin onísun-ẹ̀jẹ̀Jesu wo afọ́jú àti odi sànÀwọn Alágbàṣe KéréJesu rán àwọn méjìlá jádeJesu àti Johanu onítẹ̀bọmiÈgbé ni fún àwọn ìlú tí kò ronúpìwàdàÌsinmi fún aláàárẹ̀Olúwa ọjọ́ ìsinmiÌránṣẹ́ tí Ọlọ́run yànJesu àti BeelsebuluÀmì JonaÌyá Jesu àti àwọn arákùnrin rẹ̀Òwe afúnrúgbìnÒwe èpò àti alikamaÒwe hóró musitadi àti ìwúkàràÀlàyé òwe èpò àti alikamaÒwe ìṣúra tí a fi pamọ́ sínú ilẹ̀ àti ohun ẹ̀ṣọ́ olówó iyebíyeÒwe ti àwọ̀n ẹjaWòlíì tí kò lọ́láA bẹ́ Johanu Onítẹ̀bọmi lóríJesu bọ́ ẹgbẹ̀rún márùn-ún (5,000) ènìyànJesu rìn lójú omiOhun mímọ́ àti ohun àìmọ́Jesu bọ́ ẹgbàajì (4,000) ènìyànBíbéèrè Fún ÀmìÌwúkàrà Farisi àti SadusiPeteru jẹ́wọ́ KristiJesu sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikú ara rẹ̀Orí òkè ÌparadàÌwòsàn ọmọkùnrin ẹlẹ́mìí èṣùOwó tẹmpiliẸni tí ó tóbi jù ní ìjọba Ọ̀runÒwe àgùntàn tó sọnùArákùnrin tí ó ṣẹ̀ sí ọÒwe aláìláàánú ọmọ ọ̀dọ̀Ìkọ̀sílẹ̀Àwọn ọmọdé àti JesuỌ̀dọ́mọkùnrin ọlọ́rọ̀Òwe àwọn òṣìṣẹ́ nínú ọgbà àjàràJesu tún sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀Ẹ̀bẹ̀ ìyáAfọ́jú méjì ríranFífi ayọ̀ wọléJesu palẹ̀ Tẹmpili mọ́Igi ọ̀pọ̀tọ́ gbẹA béèrè àṣẹ tí Jesu ń lòÒwe àwọn ọmọ méjìÒwe àwọn ayálégbéÒwe àsè ìgbéyàwóSísan owó orí fún KesariÌgbéyàwó nígbà àjíǹdeÒfin tí ó ga jùlọỌmọ ta ni Kristi?Ìdí méje fún ìdájọ́Àwọn àmì òpin ayéA kò mọ ọjọ́ tàbí wákàtí náàÒwe àwọn wúńdíá mẹ́wàáÒwe tálẹ́ǹtìÀwọn àgùntàn àti ewúrẹ́Ìdìtẹ̀ mọ́ JesuA fi òróró kun Jesu lára ní BetaniJudasi gbà láti fi Jesu hànOúnjẹ alẹ́ ìkẹyìnJesu sọ pé Peteru yóò sẹ́ òunJesu ní GetsemaneA mú JesuNíwájú SahẹndiriPeteru sẹ́ JesuJudasi lọ pokùnsoJesu níwájú PilatuÀwọn ọmọ-ogun na JesuA kan Jesu mọ́ àgbélébùúIkú JesuA tẹ́ Jesu sínú ibojìÀwọn olùṣọ́ ní ibojìÀjíǹde rẹ̀Àwọn olùṣọ́ ròyìnJesu pín iṣẹ́ ńlá fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀